You are here
Home > Sponsored Post > Olu Ibogun Owu Kingom Organises Special Cross Over Prayers In Ogun State

Olu Ibogun Owu Kingom Organises Special Cross Over Prayers In Ogun State

CROSS –OVER NIGHT
IFÁ-OLÓKUN FOUNDATION PE GBOGBO ÈNÌYÀN SÍ IBI ÀDÚRÀ ÀṢEKÁGBÁ ODÚN (CROSS-OVER NIGHT) TÍ Ó MÁA WÁYÉ NI 31ST DECEMBER 2018, SÍ JANUARY 1ST 2019.
GBOGBO ÈNÌYÀN NI A PÈ O
ÀKÒRÍ: ODÚN AYỌ̀ MI
SPEAKERS: 1. CHIEF AASÀ KỌ́LÁWỌLÉ IFÁSAN¬JỌ́ (AMÚKINRỌ̀ OF ÌBÒGỤ̀N ÒWU KINGDOM)
2. CHIEF GBÉFÁGA ÌLOGBÒ ÀTI
3. CHIEF ADÉYEMÍ ỌBÁŃLÁ
SPIRITUAL FATHERS: CHIEF ÀJÀNÍ OLÚRÉBI (OLÚWO SÁŃGO)
CHIEF ADÉOYÈ FÁYÍNKÁ (OLÚWO ÌBÒGÙN) ÀTI
YÈYÉ Ọ̀ṢUN ỌLỌ́ṢUNDÉ (YÈYÉ Ọ̀ṢUN SÁŃGO)
NÍ HEAD QUARTER, AJÍGBỌ́TIFÁ TEMPLE, EWÚPẸ̀Ẹ́ Ọ̀TÀ OGUN STATE NI YÓÒ TI WÁYÉ
TÍ Ẹ BÁ Ń BỌ̀ Ẹ MÚ IYỌ̀ DÁNÍ LÁTI FI GBA ÀDÚRÀ WỌNÚ ỌDÚN TUNTUN. ÌBÀNÚJẸ́ KÌÍ BÁ IYỌ̀, ÌBÀNÚJẸ́ KÒ NÍ BÁWA O. ỌṢẸ ÌBÙKÚN ATÓRÍṢE LÁTI TÚN ẸLẸ́DÀA WA ṢE LÁTI ṢE ÀṢEYỌRÍ NÍNÚ ỌDÚN TUNTUN NÁÀ WÀ PẸ̀LÚ.
OLÚ OF ÌBÒGÙN ÒWU KINGDOM
H.R.M OBA (DR) FÁKÁYỌ̀DÉ ADÉṢÍNÀ FÁLÙÁDÉ
ÀÀRẸ ÀTI OLÙDÁSÍLẸ̀ IFÁ OLÓKUN FOUNDATION NI OLÙGBÀLEJÒ ÀTI OLÙKÉDE
FÚN ÀLÀYÉ: Ẹ PE MR DÒSÙNMÚ SÓRÍI 08024398613
AYỌ̀ LA Ó FI SỌDÚN O, ÀṢẸ

409 total views, 2 views today

dblockanny
Anidugbe Damilola is a Lifestyle blogger, Chief-Editor for Block Magazine and a seasoned journalist with vast knowledge in entertainment. He is a graduate of Mass Communication from one of the prestigious institutions in Nigeria. His love for disseminating happenings around the globe with emphasis on politics, showbiz, lifestyle, sport, entertainment, religious matters birth www.dblockanny.com.
http://www.dblockanny.com

Leave a Reply

Top